Isikiẹli 40:3 BM

3 Nígbà tí ó mú mi dé ìlú náà, mo rí ọkunrin kan tí àwọ̀ rẹ̀ dàbí idẹ. Ó sì dúró lẹ́nu ọ̀nà, ó mú okùn òwú ati ọ̀pá tí wọ́n fi ń wọn nǹkan lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:3 ni o tọ