Isikiẹli 40:41 BM

41 Tabili mẹrin wà ninu, mẹrin sì wà ní ìta, lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnu ọ̀nà; gbogbo rẹ̀ jẹ́ tabili mẹjọ. Lórí wọn ni wọ́n tí ń pa ẹran ìrúbọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:41 ni o tọ