Isikiẹli 40:43 BM

43 Wọ́n kan àwọn ìkọ́ kan tí ó gùn ní ìwọ̀n àtẹ́lẹwọ́ kan mọ́ ara tabili yíká ninu. Wọn a máa gbé ẹran tí wọn yóo bá fi rúbọ lé orí àwọn tabili náà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:43 ni o tọ