Isikiẹli 40:46 BM

46 Yàrá tí ó kọjú sí ìhà àríwá jẹ́ ti àwọn alufaa tí wọn ń mójútó pẹpẹ; àwọn ni àwọn ọmọ Sadoku. Àwọn nìkan ninu ìran Lefi ni wọ́n lè súnmọ́ OLUWA láti rúbọ sí i.

Ka pipe ipin Isikiẹli 40

Wo Isikiẹli 40:46 ni o tọ