Isikiẹli 41:13 BM

13 Lẹ́yìn náà, ó wọn Tẹmpili, ó gùn ní ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45). Àgbàlá ati ilé náà pẹlu ògiri rẹ̀ gùn ní ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45).

Ka pipe ipin Isikiẹli 41

Wo Isikiẹli 41:13 ni o tọ