Isikiẹli 41:20 BM

20 Wọ́n gbẹ́ àwòrán igi ọ̀pẹ ati kerubu sí ara ògiri náà láti ilẹ̀ títí dé òkè ìlẹ̀kùn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 41

Wo Isikiẹli 41:20 ni o tọ