Isikiẹli 42:5 BM

5 Àwọn yàrá ti àgbékà kẹta kéré, nítorí ibùjókòó-òkè ti àgbékà kẹta fẹ̀ ju àwọn tí wọ́n wà níwájú àwọn yàrá àgbékà kinni ati ti àgbékà ààrin lọ.

Ka pipe ipin Isikiẹli 42

Wo Isikiẹli 42:5 ni o tọ