Isikiẹli 42:8 BM

8 Àwọn yàrá ti gbọ̀ngàn ìta gùn ní aadọta igbọnwọ (mita 25), ṣugbọn àwọn tí wọ́n wà níwájú tẹmpili jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 50).

Ka pipe ipin Isikiẹli 42

Wo Isikiẹli 42:8 ni o tọ