Isikiẹli 45:22 BM

22 Ní ọjọ́ náà ọba yóo pa ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀ ati fún gbogbo àwọn ará ìlú.

Ka pipe ipin Isikiẹli 45

Wo Isikiẹli 45:22 ni o tọ