Isikiẹli 45:25 BM

25 “Ní ọjọ́ kẹẹdogun oṣù keje, tíí ṣe ọjọ́ keje àjọ̀dún náà, yóo pèsè irú ẹbọ kan náà fún ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, ati ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun jíjẹ ati òróró.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 45

Wo Isikiẹli 45:25 ni o tọ