Isikiẹli 46:16 BM

16 OLUWA Ọlọrun ní, “Bí ọba bá fún ọ̀kankan ninu àwọn ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀bùn lára ilẹ̀ rẹ̀, ilẹ̀ náà di ti àwọn ọmọ rẹ̀, ó di ohun ìní wọn tí wọ́n jogún.

Ka pipe ipin Isikiẹli 46

Wo Isikiẹli 46:16 ni o tọ