Isikiẹli 47:19 BM

19 “Ní ìhà gúsù, ilẹ̀ yín yóo lọ láti Tamari dé àwọn odò Meriba Kadeṣi, títí yóo fi kan odò Ijipti títí lọ dé Òkun-ńlá. Èyí ni yóo jẹ́ ààlà ilẹ̀ náà ní apá ìhà gúsù.

Ka pipe ipin Isikiẹli 47

Wo Isikiẹli 47:19 ni o tọ