Isikiẹli 5:10 BM

10 Baba yóo máa pa ọmọ wọn jẹ láàrin yín; ọmọ yóo sì máa pa àwọn baba jẹ. N óo dájọ́ fun yín, n óo fọ́n gbogbo àwọn tí ó kù ninu yín káàkiri igun mẹrẹẹrin ayé.

Ka pipe ipin Isikiẹli 5

Wo Isikiẹli 5:10 ni o tọ