Isikiẹli 7:11 BM

11 Ìwà ipá hù, ó dàgbà, ó di ọ̀pá ìwà ibi; bí ẹ ti pọ̀ tó, ẹ kò ní ṣẹ́ku ẹyọ ẹnìkan, àtẹ̀yin ati àwọn ohun ìní yín, ati ọrọ̀ yín ati ògo yín.

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:11 ni o tọ