Isikiẹli 7:24 BM

24 N óo kó àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n burú jùlọ wá, wọn óo wá gba ilé wọn. N óo fi òpin sí ìgbéraga àwọn alágbára wọn, wọn yóo sì sọ àwọn ibi mímọ́ wọn di eléèérí.

Ka pipe ipin Isikiẹli 7

Wo Isikiẹli 7:24 ni o tọ