Isikiẹli 11:12 BM

12 Ẹ óo mọ̀ pé èmi ni OLUWA; nítorí pé ẹ kò rìn ninu ìlànà mi, ẹ kò sì pa òfin mi mọ́, ṣugbọn ẹ ti gba àṣà àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n yi yín ká.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 11

Wo Isikiẹli 11:12 ni o tọ