Isikiẹli 16:18 BM

18 O mú aṣọ rẹ tí a ṣe ọnà sí lára, o dà á bò wọ́n. O gbé òróró ati turari mi kalẹ̀ níwájú wọn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:18 ni o tọ