Isikiẹli 16:31 BM

31 O mọ ilé oriṣa sí òpin gbogbo òpópó, o sì ń kọ́ ibi ìrúbọ sí gbogbo gbàgede. Sibẹ o kò ṣe bí àwọn alágbèrè, nítorí pé o kò gba owó.

Ka pipe ipin Isikiẹli 16

Wo Isikiẹli 16:31 ni o tọ