Isikiẹli 25:12 BM

12 OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí àwọn ará Edomu gbẹ̀san lára àwọn ará Juda, wọ́n sì ṣẹ̀ nítorí ẹ̀san tí wọ́n gbà.

Ka pipe ipin Isikiẹli 25

Wo Isikiẹli 25:12 ni o tọ