13 N óo nawọ́ ìyà sí Edomu, n óo pa ati eniyan ati ẹranko inú rẹ̀ run. N óo sọ ọ́ di ahoro láti Temani títí dé Dedani. Ogun ni yóo pa wọ́n.
Ka pipe ipin Isikiẹli 25
Wo Isikiẹli 25:13 ni o tọ