Isikiẹli 37:11 BM

11 OLUWA bá sọ fún mi pé, “Ìwọ ọmọ eniyan, àwọn ọmọ Israẹli ni àwọn egungun wọnyi. Wọ́n ń sọ pé, ‘Egungun wa ti gbẹ; kò sí ìrètí fún wa mọ́, a ti pa wá run patapata.’

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:11 ni o tọ