Isikiẹli 37:12 BM

12 Nítorí náà, sọ àsọtẹ́lẹ̀ kí o wí fún wọn pé OLUWA Ọlọrun ní, ‘N óo ṣí ibojì yín; n óo sì gbe yín dìde, ẹ̀yin eniyan mi, n óo mu yín pada sí ilé, ní ilẹ̀ Israẹli.

Ka pipe ipin Isikiẹli 37

Wo Isikiẹli 37:12 ni o tọ