Jeremaya 1:1 BM

1 Ọ̀rọ̀ Jeremaya, ọmọ Hilikaya, ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí ó wà ní Anatoti, ní ilẹ̀ Bẹnjamini nìyí.

Ka pipe ipin Jeremaya 1

Wo Jeremaya 1:1 ni o tọ