Jeremaya 1:10 BM

10 Mo ti fi ọ́ ṣe orí fún àwọn orílẹ̀-èdè ati ìjọba lónìí,láti fà wọ́n tu ati láti bì wọ́n lulẹ̀,láti pa wọ́n run ati láti bì wọ́n ṣubú,láti tún wọn kọ́ ati láti gbé wọn ró.”

Ka pipe ipin Jeremaya 1

Wo Jeremaya 1:10 ni o tọ