Jeremaya 11:12 BM

12 Ó ní àwọn ìlú Juda ati àwọn tí wọn ń gbé Jerusalẹmu yóo ké pe àwọn oriṣa tí wọn ń sun turari sí, ṣugbọn àwọn oriṣa kò ní lè gbà wọ́n lọ́jọ́ ìṣòro.

Ka pipe ipin Jeremaya 11

Wo Jeremaya 11:12 ni o tọ