Jeremaya 12:13 BM

13 Ọkà baali ni wọ́n gbìn, ṣugbọn ẹ̀gún ni wọ́n kórè.Wọ́n ṣe làálàá, ṣugbọn wọn kò jèrè kankan.Ojú yóo tì wọ́n nígbà ìkórè,nítorí ibinu gbígbóná OLUWA.”

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:13 ni o tọ