Jeremaya 12:9 BM

9 Ṣé ogún mi ti dàbí ẹyẹ igún aláwọ̀ adíkálà ni?Ṣé àwọn ẹyẹ igún ṣùrù bò ó ni?Ẹ lọ pe gbogbo àwọn ẹranko igbó jọ,ẹ kó wọn wá jẹun.

Ka pipe ipin Jeremaya 12

Wo Jeremaya 12:9 ni o tọ