25 Èyí ni ìpín yín,ìpín tí mo ti yàn fun yín,nítorí pé ẹ ti gbàgbé èmi OLUWA, ẹ sì gbẹ́kẹ̀lé ọlọrun èké.
Ka pipe ipin Jeremaya 13
Wo Jeremaya 13:25 ni o tọ