Jeremaya 15:3 BM

3 Oríṣìí ìparun mẹrin ni n óo jẹ́ kí ó dé bá wọn: idà óo pa wọ́n, ajá óo fà wọ́n ya, àwọn ẹyẹ ati àwọn ẹranko óo jẹ wọ́n ní àjẹrun.

Ka pipe ipin Jeremaya 15

Wo Jeremaya 15:3 ni o tọ