Jeremaya 16:11 BM

11 Kí o dá wọn lóhùn pé, nítorí pé àwọn baba wọn ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n ń tẹ̀lé àwọn ọlọrun mìíràn, wọ́n ń sìn wọ́n, wọ́n sì ń bọ wọ́n.

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:11 ni o tọ