Jeremaya 16:17 BM

17 Nítorí pé mò ń wo gbogbo ohun tí wọn ń ṣe, kò sí èyí tí n kò rí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀ṣẹ̀ wọn kò sápamọ́ fún mi.

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:17 ni o tọ