Jeremaya 16:3 BM

3 Nítorí ohun tí OLUWA sọ nípa àwọn ọmọkunrin ati àwọn ọmọbinrin tí a bí ní ibí yìí, ati nípa ìyá tí ó bí wọn, ati baba tí a bí wọn fún ni pé,

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:3 ni o tọ