Jeremaya 17:14 BM

14 Wò mí sàn, OLUWA, ara mi yóo sì dá,gbà mí, n óo sì bọ́ ninu ewu.Nítorí pé ìwọ ni mò ń yìn.

Ka pipe ipin Jeremaya 17

Wo Jeremaya 17:14 ni o tọ