Jeremaya 2:37 BM

37 Ẹ óo ká ọwọ́ lérí ninígbà tí ẹ óo bá jáde níbẹ̀.Nítorí OLUWA ti kọ àwọn tí ẹ gbójúlé,wọn kò sì ní ṣe yín níre.”

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:37 ni o tọ