Jeremaya 20:12 BM

12 OLUWA àwọn ọmọ ogun, ìwọ tíí dán olódodo wò,ìwọ tí o mọ ọkàn ati èrò eniyan.Gbẹ̀san lára wọn kí n fojú rí i,nítorí ìwọ ni mo fi ọ̀rọ̀ mi lé lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 20

Wo Jeremaya 20:12 ni o tọ