Jeremaya 20:18 BM

18 Kí ló dé tí wọn bí mi sáyé?Ṣé kí n lè máa fojú rí ìṣẹ́ ati ìbànújẹ́ ni?Kí gbogbo ọjọ́ ayé mi lè kún fún ìtìjú?

Ka pipe ipin Jeremaya 20

Wo Jeremaya 20:18 ni o tọ