13 OLUWA ní,“Ẹ wò ó, mo dojú ìjà kọ yín,ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé àfonífojì,tí ó dàbí àpáta tí ó yọ sókè ju pẹ̀tẹ́lẹ̀ lọ,ẹ̀yin tí ẹ̀ ń wí pé,‘Ta ló lè dojú ìjà kọ wá?Àbí ta ló lè wọ inú odi ìlú wa?’
Ka pipe ipin Jeremaya 21
Wo Jeremaya 21:13 ni o tọ