5 Èmi fúnra mi ni n óo ba yín jà. Ipá ati agbára, pẹlu ibinu ńlá, ati ìrúnú gbígbóná ni n óo fi ba yín jà.
Ka pipe ipin Jeremaya 21
Wo Jeremaya 21:5 ni o tọ