Jeremaya 22:15 BM

15 Ṣé ilé kedari tí o kọ́ ni ó sọ ọ́ di ọba?Wo baba rẹ, ṣé kò rí jẹ ni,tabi kò rí mu?Ṣebí ó ṣe ẹ̀tọ́ ati òdodo,ṣebí ó sì dára fún un.

Ka pipe ipin Jeremaya 22

Wo Jeremaya 22:15 ni o tọ