Jeremaya 22:17 BM

17 Ṣugbọn níbi èrè aiṣododo nìkan ni ojú ati ọkàn yín ń wà,níbi kí ẹ máa pa aláìṣẹ̀, kí ẹ máa ni eniyan lára,kí ẹ sì máa hùwà ìkà.

Ka pipe ipin Jeremaya 22

Wo Jeremaya 22:17 ni o tọ