Jeremaya 22:20 BM

20 ẹ gun orí òkè Lẹbanoni lọ, kí ẹ kígbe.Ẹ dúró lórí òkè Baṣani, kí ẹ pariwo gidigidi,ẹ kígbe láti orí òkè Abarimu,nítorí pé a ti pa gbogbo àwọn alájọṣe yín run.

Ka pipe ipin Jeremaya 22

Wo Jeremaya 22:20 ni o tọ