Jeremaya 23:28 BM

28 Kí àwọn wolii tí wọn lá àlá máa rọ́ àlá wọn, ṣugbọn ẹni tí ó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, kí ó sọ ọ́ pẹlu òtítọ́. Báwo ni a ṣe lè fi ìyàngbò wé ọkà?

Ka pipe ipin Jeremaya 23

Wo Jeremaya 23:28 ni o tọ