38 Bíi kinniun tí ó fi ihò rẹ̀ sílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni OLUWA fi àwọn eniyan rẹ̀ sílẹ̀,ilẹ̀ wọn sì ti di ahoronítorí idà apanirun ati ibinu gbígbóná OLUWA.
Ka pipe ipin Jeremaya 25
Wo Jeremaya 25:38 ni o tọ