Jeremaya 27:6 BM

6 Ó ní òun ti fún Nebukadinesari, ọba Babiloni iranṣẹ òun, ní gbogbo àwọn ilẹ̀ wọnyi, òun sì ti fún un ni àwọn ẹranko inú igbó kí wọn máa ṣe iranṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 27

Wo Jeremaya 27:6 ni o tọ