Jeremaya 28:3 BM

3 Kí ó tó pé ọdún meji, òun óo kó gbogbo ohun èlò tẹmpili òun pada, tí Nebukadinesari ọba Babiloni kó láti ibí yìí lọ sí Babiloni.

Ka pipe ipin Jeremaya 28

Wo Jeremaya 28:3 ni o tọ