Jeremaya 29:7 BM

7 Ẹ máa wá alaafia ìlú tí mo ko yín lọ, ẹ máa gbadura sí OLUWA fún un, nítorí pé ninu alaafia rẹ̀ ni ẹ̀yin náà yóo ti ní alaafia.

Ka pipe ipin Jeremaya 29

Wo Jeremaya 29:7 ni o tọ