Jeremaya 30:20 BM

20 Àwọn ọmọ wọn yóo rí bí wọn ti rí ní àtijọ́,àwọn ìjọ wọn yóo fi ìdí múlẹ̀ níwájú mi.N óo sì fi ìyà jẹ gbogbo àwọn tí wọn ń ni wọ́n lára.

Ka pipe ipin Jeremaya 30

Wo Jeremaya 30:20 ni o tọ