14 N óo fún àwọn alufaa ní ọpọlọpọ oúnjẹ,n óo sì fi oore mi tẹ́ àwọn eniyan mi lọ́rùn.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Ka pipe ipin Jeremaya 31
Wo Jeremaya 31:14 ni o tọ