Jeremaya 31:36 BM

36 Òun ló sọ pé, àfi bí àwọn àṣẹ wọnyi bá yipada níwájú òun,ni àwọn ọmọ Israẹli kò fi ní máa jẹ́ orílẹ̀-èdè títí lae.

Ka pipe ipin Jeremaya 31

Wo Jeremaya 31:36 ni o tọ