Jeremaya 32:1 BM

1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ ní ọdún kẹwaa tí Sedekaya jọba ní Juda, tí ó jẹ́ ọdún kejidinlogun tí Nebukadinesari jọba.

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:1 ni o tọ